Lúùkù 12:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni nínú yín nípa àníyàn ṣíṣe tí ó lè fi ìgbọ̀nwọ́ kan kún ọjọ́ ìgbé ayé rẹ̀?

Lúùkù 12

Lúùkù 12:20-34