Lúùkù 12:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

sì wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Nítorí náà mo wí fún yín pé, ẹ má ṣe ṣàníyàn nítorí ọkàn yín pé, kínni ẹ̀yin ó fi bora.

Lúùkù 12

Lúùkù 12:21-23