Lúùkù 11:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin Farisí, àgàbàgebè! Nítorí tí ẹ̀yin fẹ́ ipò ọlá nínú sínágọ́gù, àti ìkíni ní ọjà.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:39-46