Lúùkù 11:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sí ẹnìkan, nígbà tí ó bá tan fìtílà tan, tí i gbé e sí ìkọ̀kọ̀, tàbí sábẹ́ òṣùwọ̀n, bí kò ṣe sórí ọ̀pá fìtílà, kí àwọn tí ń wọlé baà lè má a rí ìmọ́lẹ̀.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:23-40