Lúùkù 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

E dúró sínú ilé yẹn, kí ẹ máa jẹ, kí ẹ sì máa mu ohunkóhun tí wọ́n bá fifún yín; nítorí ọ̀yà alágbàṣe tọ́ sí i, Ẹ má ṣe ṣí láti ilé dé ilé.

Lúùkù 10

Lúùkù 10:4-9