Lúùkù 10:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kòńgẹ́ àkókò yìí ni àlùfáà kan sì ń sọ̀kalẹ̀ lọ lọ́nà náà: nígbà tí ó sì rí i ó kọjá lọ níhà kejì.

Lúùkù 10

Lúùkù 10:30-35