Lúùkù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí i, èmí fún yín ní àṣẹ láti tẹ ejò àti àkéekèé mọ́lẹ̀, àti lórí gbogbo agbára ọ̀tá: kò sì sí ohun kan bí ó ti wù tí ó ṣe, tí yóò pa yín lára.

Lúùkù 10

Lúùkù 10:14-20