Lúùkù 10:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìwọ, Kápánáúmù, a ó ha gbé ọ ga dé òkè ọ̀run? A ó rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ dé isà òkú.

Lúùkù 10

Lúùkù 10:9-17