Lúùkù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìṣe àwọn àlùfáà, ipa tirẹ̀ ni láti máa fi tùràrí jóná, nígbà tí ó bá wọ inú tẹ́ḿpìlì Olúwa lọ.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:6-16