Lúùkù 1:80 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ náà sì dàgbà, ó sì le ní ọkàn, ó sì ń gbé ní ijù títí ó fi di ọjọ́ ìfihàn rẹ̀ fún Ísírẹ́lì.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:71-80