Lúùkù 1:67 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sakaráyà baba rẹ̀ sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, ó sì ṣọtẹ́lẹ̀, ó ní:

Lúùkù 1

Lúùkù 1:65-71