Lúùkù 1:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti fi agbára hàn ní apá rẹ̀;Ó ti tú àwọn onígberaga ká ní ìrònú ọkàn wọn.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:47-53