Lúùkù 1:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ké ní ohùn rara, ó sì wí pé, “Alúbùkún fún ni ìwọ nínú àwọn obìnrin, alábùkúnfún sì ni ọmọ tí ìwọ yóò bí.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:36-51