Lúùkù 1:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì náà sì dáhùn ó sì wí fún un pé, “Ẹ̀mí Mímọ́ yóò tọ̀ ọ́ wá, àti agbára Ọ̀gá-ògo jùlọ yóò sìji bò ọ́. Nítorí náà ohun mímọ́ tí a ó ti inú rẹ bí, Ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè é.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:34-43