Lúùkù 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì náà sì tọ̀ ọ́ wá, ó ní, “Àlààáfíà, ìwọ ẹni tí a kọjú sí ṣe ní oore, Olúwa ńbẹ pẹ̀lú rẹ”

Lúùkù 1

Lúùkù 1:22-34