Lúùkù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àní gẹ́gẹ́ bí àwọn ìránṣẹ́ ọ̀rọ̀ náà tí ó ṣe ojú wọn láti ìbẹ̀rẹ̀ ti fi lé wa lọ́wọ́.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:1-5