Lúùkù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ó sì yí ènìyàn púpọ̀ padà nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí Olúwa Ọlọ́run wọn.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:8-23