Lúùkù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì jẹ́ ayọ̀ àti ìdùnnú fún ọ: ènìyàn púpọ̀ yóò sì yọ̀ sí ìbí rẹ.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:13-17