Léfítíkù 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì sì wá síbi pẹpẹ, ó pa akọ ọmọ màlúù fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀.

Léfítíkù 9

Léfítíkù 9:2-17