Léfítíkù 8:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dé e ní fìlà, ó sì fi àwo wúrà tíí ṣe adé mímọ́ ṣíwájú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Léfítíkù 8

Léfítíkù 8:4-12