Léfítíkù 8:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì tún mú àwọn ọmọ Árónì wá ṣíwájú, ó sì mú ẹ̀jẹ̀ díẹ̀ ó fi sí etí ọ̀tún wọn, àtàǹpàkò ọwọ́ ọ̀tún wọn, ó sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ yí pẹpẹ náà ká.

Léfítíkù 8

Léfítíkù 8:16-32