Léfítíkù 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi omi fọ gbogbo nǹkan inú àti ẹṣẹ̀ rẹ̀, ó sì sun odidi àgbò náà lórí pẹpẹ bí ẹbọ sísun òórùn dídùn, ẹbọ tí a fi iná se sí Olúwa gẹ́gẹ́ bí Olúwa tí pàṣẹ fún Mósè.

Léfítíkù 8

Léfítíkù 8:17-30