Léfítíkù 8:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì pa àgbò náà, ó sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yí pẹpẹ náà ká.

Léfítíkù 8

Léfítíkù 8:18-26