Léfítíkù 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè tún mú gbogbo ọ̀rá tó bo nǹkan inú, èyí tó bo ẹ̀dọ̀, kíndìnrín méjèèjì àti ọ̀rá wọn, ó sì sun gbogbo rẹ̀ lórí pẹpẹ.

Léfítíkù 8

Léfítíkù 8:9-23