Léfítíkù 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbi tí wọn ti ń pa ẹran ẹbọ sísun ni kí ẹ ti pa ẹran ẹbọ ẹ̀bi, kí ẹ sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yí pẹpẹ náà ká.

Léfítíkù 7

Léfítíkù 7:1-5