Léfítíkù 6:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Pàṣẹ fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé: Èyí ni ìlànà fún ẹbọ sísun; ẹbọ sísun gbọdọ̀ wà lórí pẹpẹ láti alẹ́ di òwúrọ̀, kí iná sì máa jó lórí pẹpẹ

Léfítíkù 6

Léfítíkù 6:1-18