Léfítíkù 6:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ pèsè rẹ̀ pẹ̀lú òróró nínú àwo fífẹ̀, ẹ pò ó pọ̀ dáradára, kí ẹ sì gbé ọrẹ ohun jíjẹ náà wá ní ègé kéé-kèè-kéé bí òórùn dídùn sí Olúwa.

Léfítíkù 6

Léfítíkù 6:17-30