Léfítíkù 6:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyíkéyí nínú àwọn ọmọkùnrin ìran Árónì ló le jẹ ẹ́. Èyí ni ìpín rẹ tí ó gbọdọ̀ máa ṣe déédé lára àwọn ẹbọ tí a fi iná sun sí Olúwa láti ìrandíran. Ohunkóhun tí ó bá kàn án yóò di mímọ́.”

Léfítíkù 6

Léfítíkù 6:16-22