Léfítíkù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ó sì wọ́n díẹ̀ lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ náà sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, ìyókù ẹ̀jẹ̀ náà ni kí ó ro sí ìṣàlẹ̀ pẹpẹ. Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.

Léfítíkù 5

Léfítíkù 5:1-13