Léfítíkù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ẹnìkan bá dẹ́ṣẹ̀ tí ó sì ṣe ohun tí kó yẹ ko ṣe sí ọ̀kan nínú òfin Olúwa, bí kò tilẹ̀ mọ̀, ó jẹ̀bi, yóò sì ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀

Léfítíkù 5

Léfítíkù 5:16-19