Léfítíkù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíndìnrín méjèèjì pẹ̀lú ọ̀rá wọn tí ń bẹ lẹ́bàá ìhà àti ọ̀rá tó bo ẹ̀dọ̀, kí ó yọ ọ́ pẹ̀lú kíndìnrín.

Léfítíkù 4

Léfítíkù 4:2-18