Léfítíkù 4:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó sun gbogbo ọ̀rá rẹ̀ lórí pẹpẹ bí ó se sun ọ̀rá ọrẹ àlàáfíà. Báyìí ní àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún ẹsẹ ọkùnrin náà, a ó sì dárí jìn-ín.

Léfítíkù 4

Léfítíkù 4:21-35