Léfítíkù 4:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lórí ewúrẹ́ náà, kí ó sì pa á níbi tí wọ́n ti ń pa ẹran ẹbọ sísun níwájú Olúwa. Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.

Léfítíkù 4

Léfítíkù 4:18-33