Léfítíkù 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó sì ṣe akọ ọmọ màlúù yìí gẹ́gẹ́ bí ó ṣe ṣe akọ màlúù tó wà fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀. Báyìí ni àlùfáà yóò ṣe ṣe ètùtù fún wọn, á ó sì dárí jìn wọ́n.

Léfítíkù 4

Léfítíkù 4:15-28