Léfítíkù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, kí ó sì pa á níwájú àgọ́ ìpàdé, kí àwọn ọmọ Árónì wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹran náà yí pẹpẹ ká.

Léfítíkù 3

Léfítíkù 3:4-13