Léfítíkù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíndìnrín méjèèjì pẹ̀lú ọ̀rá tí ń bẹ lẹ́bàá ìhà rẹ̀ àti ọ̀rá tí ó bo ẹ̀dọ̀, kí o yọ ọ́ jáde pẹ̀lú kíndìnrín.

Léfítíkù 3

Léfítíkù 3:1-13