Léfítíkù 27:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Bí ẹ̀jẹ́ tí ó jẹ́ bá jẹ́ ẹranko èyí tí ó jẹ́ ìtẹ́wọ̀gbà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fún Olúwa, irú ẹran bẹ́ẹ̀ tí a bá fi fún Olúwa di mímọ́.

Léfítíkù 27

Léfítíkù 27:4-14