Léfítíkù 27:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹni náà bá jẹ́ ọmọ oṣù kan sí ọdún márùn-ún, kí iye owó rẹ̀ jẹ́ òṣùwọ̀n ṣékélì fàdákà márùn-ún fún ọkùnrin àti òṣùwọ̀n ṣékélì fàdákà mẹ́ta fún obìnrin.

Léfítíkù 27

Léfítíkù 27:1-10