Léfítíkù 27:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a bá fi ilẹ̀ náà sílẹ̀ ní ọdún ìdásílẹ̀ yóò di mímọ́ gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ tí a fi fún Olúwa. Yóò sì di ohun ìní àlùfáà.

Léfítíkù 27

Léfítíkù 27:16-31