Léfítíkù 27:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹni náà bá fẹ́ rà á padà: ó gbọdọ̀ san iye owó rẹ̀ àti ìdá ogún iye owó náà láfikún.

Léfítíkù 27

Léfítíkù 27:12-20