Léfítíkù 26:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ̀nyí ni òfin àti ìlànà tí Olúwa fún Mósè ní orí òkè Sínáì láàrin òun àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:41-46