Léfítíkù 26:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí tó mú mi lòdì sí wọn tí mo fi kó wọn lọ sí ilẹ̀ àwọn ọ̀ta wọn. Nígbà tí wọ́n bá rẹ àìkọlà àyà wọn sílẹ̀ tí wọ́n bá sì gba ìbáwí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:39-46