Léfítíkù 26:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀n ìgbà tí ẹ kò lò ó, ilẹ̀ náà yóò ní ìsinmi tí kò ní lákòókò ìsinmi rẹ̀ lákókò tí ẹ fi ń gbé orí rẹ̀.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:27-39