Léfítíkù 26:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò rán àwọn ẹranko búburú sí àárin yín, wọn yóò sì pa àwọn ọmọ yín, wọn yóò run agbo ẹran yín, díẹ̀ nínú yín ni wọn yóò ṣẹ́kù kí àwọn ọ̀nà yín lè di ahoro.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:16-28