Léfítíkù 26:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ó máa lo agbára yín lásán torí pé ilẹ̀ yín kì yóò so èso, bẹ́ẹ̀ ni àwọn igi yín kì yóò so èso pẹ̀lú.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:11-21