Èmi yóò dojú kọ yín títí tí ẹ̀yin ó fi di ẹni ìkọlù; àwọn tí ó kóríra yín ni yóò sì ṣe àkóso lórí yín. Ìbẹ̀rù yóò mú yín débi pé ẹ̀yin yóò máa sá kákìkiri nígbà tí ẹnikẹ́ni kò lé yín.