Léfítíkù 25:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà, kí ẹ fọn fèrè ní gbogbo ibikíbi ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kéje ní ọjọ́ ìwẹ̀nùmọ́. Ní ọjọ́ ètùtù yìí, ẹ fọn fèrè yíká gbogbo ilẹ̀ yín.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:4-17