Léfítíkù 25:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọdún rẹ̀ kò bá pọ̀ sí àkókò ìdásílẹ̀, kí ó ṣe ìṣírò rẹ̀, kí ó sì san owó náà bí iye ìṣírò rẹ̀.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:47-55