Léfítíkù 25:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí òun àti olówó rẹ̀ ka iye ọdún tí ó ta ara rẹ̀ títí dé ọdún ìdásílẹ̀ kí iye owó ìdásílẹ̀ rẹ̀ jẹ́ iye tí wọ́n ń san lórí alágbàṣe fún iye ọdún náà.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:44-55