Léfítíkù 25:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ lè fi wọ́n sílẹ̀ bí ogún fún àwọn ọmọ yín; Wọ́n sìle sọ wọ́n di ẹrú títí láé. Ṣùgbọ́n ẹ kò gbọdọ̀ rorò mọ́ ọmọ Ísírẹ́lì kankan.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:36-51